ÌFILÓLÈ ÀJO ÀDÁNI TÍ KÒ NÍ ÈRÈJE NÍNÚ SÙGBÓN FÚN ÀNFÀNÍ ARÁ ÌLÚ LÁTI OWÓ DÓKÍTÀ ONÍSÈGÙN ÒYÌNBÓ ÀTI PÀRÀKÒYÍ ONÎSÒWÒ OMÓLÁJAIYÉ SUNDAY ABRAHAM.

 ÌFILÓLÈ ÀJO ÀDÁNI TÍ KÒ NÍ ÈRÈJE NÍNÚ SÙGBÓN FÚN ÀNFÀNÍ ARÁ ÌLÚ LÁTI OWÓ DÓKÍTÀ ONÍSÈGÙN ÒYÌNBÓ ÀTI PÀRÀKÒYÍ ONÎSÒWÒ OMÓLÁJAIYÉ SUNDAY ABRAHAM.





Esè kò gba èrò lóòní ojó kerìnlá osù kerìn, egbèrun odún àti èrìnlélógun ní gbòngàn ìgbafé kan ní ìlú ilé ifé. onísègùn Òyìnbó Sunday OMÓLÁJAIYÉ dawo ìdùnú pèlú bí àlá re se wá sí ìmúse láti lè jé ìrànlówó fún ògòrò ènìyàn látàrí ìrírí rè tí ò ti ní látèhìn wá. Ó mo rírì Olórun Oba pèlú bó se fún ní àseyori lórí ìdáwólé oun bó ti lè jé wípé kò rorùn ní àkókò tí òun gun àkàbà ìse rere rè, sùgbón tí Olórun jé ko se se fún òun, ìdí nìyí tí òun kò fi ní síwó oore í se. Ogba béè ló so àkomònà àjo àdáni tíkò ní èrèje nínú pèlú ègbè àti ìdáhùn *"ire Olú ... Tilé t'oko"* , tí ó sì so ìtumo àsíá àjo àdáni ìdí tó se jé orí àgbò.



Ó so nínú òrò rè wípé òun tí níi lókàn láti ìgbà pípé wá fún irú ànfàní bayíì láti máa ran òpòlopò àwon ènìyàn lówó ní èyí tí Olórun sì jé kí ó se é se. ogba béè ló tún so nínú àpilèko rè wípé kí ìjoba àpapò àti ti ìpínlè kí ó má se síwó mímú ìdàgbàsókè bá eka kòòkan láti lè mún ayé rorùn fún ará ìlú. Tí ó sì tèsìwájú wípé èyí tí òun se yìí kí òun fi kún ìjoba lówó ni, ogba béè ló tún se àkàwé màmá rè bíi afúni, tí ó sì se àkàwé fífifúni tie náà gégé bí ìwà tí òun jogun latí Ara mama òun





Lara àwon tí won yé ètò yìí sí ni komísánà fún ètò èkó ní ìpínlè òsun, Hon. Dipo Eluwole, komísánà fún òrò ìsèjoba Hon. Dr. Bíyì Odunlade, Olùdamóràn-àn gómìnà lórí òrò ìrónilágbára àti èyáwó Hon Isaac Durojaiye tí òpò mò sí Sikomole, obawara Ile ife , Jagunosin Olóyè Aworeni, Jimi Bada Vanguard forum,  àwon ladies of substance  ati òpòlopò àwon àlejò jànkànkankan. Nínú eyi ní òkòòkan àwon àlejò ti lú, Ààre DÓKÍTÀ OMÓLÁJAIYÉ Sunday lógo enu, fun akitiyan rè Lórí àti mún igbe ayé tò rorùn bá ará ìlù ati bákan náà níní ará ìlú lóókan pèlú ìrànlówó láì ní èrèje nínú.



Léhìn naa ni won se àfihàn àwon olùdarí eka kòòkàn pélù ìbúra fún won láti enu ààre àjó àdáni tíkòní èrèje nínú, ònísègùn òyìnbó nì àti pàràkòyí onísòwò ní ilè yíì àti ní òkè òkun

OMÓLÁJAIYÉ Sunday Abraham. Lárá àwon ofisìì tí wón fi lólè ni eka ìlera, eré ìdárayá, ètò èkó,ìsúná, òfin, ètò fún àwon obìrin àti eto ìgbafé.

Léhìn ohun gbogbo ni olórí gbogbo èka lábé àjo àdáni tíkòní èrèje nínú Hon. Seun Adediwura dúpé lówó gbogbo àwon tíwón wa síbi ètò yìí, tí ó sì fi dáwon lójú wípé ètò náà kò nó já Ara ìlú nítànmó òn.



*E-signed*

*Dr Abraham Sunday Omolajaye*

*President Omolajaye Foundation*


©2024

Comments

Popular posts from this blog

Breaking News: former Governor of Osun State, Ọgbẹni AbdulRauf Aregbesola and his Loyalists Finally Pull out of All Progressive Party (APC), to announce new party soon.

MASS DEFECTION ROCKS OSUN APC AS THEIR LEADERS DEFECT TO PDP IN ILESA EAST

Electricity Tariff: How To Check If You’re In Band A, B, C, D or E